Baba omo ti ajo NYSC gbe omo re lo si ilu Katsina lati lo sinru ilu ti fariga wi pe oun o ni yaju oun sile ki talubo o kowo. Sebi enu eni ni eniyan fi n ko meje. Owo ara eni la si fi n tun iwa owo eni se. Kosi obi ti yoo ri ile iku nile ti yoo ti omo re sii lailai.
Okunrin naa ti seleri lati ji si ofiisi ajo NYSC laaro oni [31-07-14] lati koro oju sibi ti won gbe omo re lo eleyii ti ko te lorun.
0 comments:
Post a Comment