Smiley face

Ija Asewo Onidodo Ni Ilu Eko

Ile otin kan ni ilu Eko ni wahala ti sele laaarin anti onidodo ati booda Emeka to n je dodo lawin.

Obirin asewo yii lo se alaye fun awon eniyan wi pe Onibara oun daada ni Emeka. O ni omokunrin naa je dodo lawin ni ko ba ba fe sanwo dodo mo.


Omobirin yii tun se alaye siwaju wi pe sisa ni Emeka n sa fun oun lati ojo to ti be oun wi pe ko si owo lowo oun sugbon dodo n wu oun je ni oun naa ba din dodo Ikire to dun fun-un. Gege bi oro re, ajemoju ni Mr Emeka je dodo naa o si gbadun re daada nitori wi pe dodo to ni sugar ninu ni.

"Oniroyin, e gbe wa saye. Oju o ti mi rara. Dodo ni mo n ta. Emi ni mo si ni dodo mi. Bawo ni eniyan o se je dodo mi ti ko ni sanwo fun mi. O ni yii ni maa gba owo mi, ko ni dola," oro enu Anti Asewo Onidodo.

Sugbon ohun ti Emeka so fun awon ore ti won jo n mu otin ni wi pe oun san owo fun omobirin naa lojo ti oun je dodo. Emeka so wi pe o soro ki eniyan je dodo l'Eko lai sanwo, ko posibu rara. Ati wi pe omobirin naa fe lo 419 fun oun ni.

E gbo esi anti onidodo.

"Owo moto lasan ni Oloriburuku ara re fun mi ki se owo dodo o. Se five hundred naira ni won je dodo l'Eko ni? Abi iku fe pa mother re ni?' Ti five thousand mi ko ba pe wa ri skamara lonii yii.'
posted from Bloggeroid
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. eleyii tun ga ooo. Anti onidodo ikire. Olayemi Oniroyin, se e de sure wi pe kii se eyin gan le je dodo lai sanwo? lol

    ReplyDelete