Ikede pataki: Wizkid ti kede fun awon ololufe re wi pe oun ti wo ilu London fun akotun orin ati ilu to gbamuse. Ilu Amerika ni Wizkid gba wo ilu Biritiko.

Bakan naa ni Mercy Aigbe ni oun ti pada si enu ise lakotun. Koda, oni enu ise nla kan ni oun wa bayii nibi ti oun ti n kopa ninu sinima alarinrin kan ti ko ni pe jade.

Awon ikede meji ti mo ni fun yin ni yii.

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment