Iroyin Keyeefi: Won Ti Ri Iho Nla Kan Ni Ikangun Aye Olayemi Oniroyin 7/16/2014 07:52:00 pm Edit Se kii se wi pe opin aye ti de tan? Awon onimo sayensi kan ti se awari koto nla kan ni ikangun aye eleyii to jin koja oye enikeni. Iwadii si n tesiwaju nipa ohun to sokunfa koto nla naa ati ewu to ro mo o. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Iroyin Keyeefi: Won Ti Ri Iho Nla Kan Ni Ikangun Aye Reviewed by Olayemi Oniroyin on 7/16/2014 07:52:00 pm Rating: 5
0 comments:
Post a Comment