Bi awon olorin se ran awon oloselu lowo bee naa ni awon onise tiata polongo won. Iroyin Kunle Afolayan taa gbo tele ni wi pe o n se igbelaruge awon ise rere Ogbeni Rauf Aregbesola to je gomina Ipinle Osun.
Sodiafo, ti Kunle ba wa ni oun gbadun ara oun lodo Tinubu, o ye ko ti ye yin.
Aofa? Se eyin naa n gbadun ara yin ni be un?
0 comments:
Post a Comment