
Ogbontarigi agbaboolu fun ile Brazil, Neymar ti dagbere bayii fun idije boolu agbaye ti n lo lowo ni ilu baba pelu bi omo ile Colombia, Juan Zuniga se fi orukun gun leyin ninu ifesewonse to waye laaarin won nibi ti Brazil ti bori pelu ayo meji si ookan.

Dokita ti n toju Neymar si ti fi ye wa wi pe yoo to bi ose merin si mefa ki omokunrin naa to le gbadun daada lati le pada si ori papa.
'The exact time (to play again) can be four to six weeks, but it is
too early to confirm this. Let's wait for other tests. This is the first
diagnosis we had. Initially, we know he will not be able to play.’ Dokita

Omo agbaboolu Colombia to sokunfa isele naa ti salaye fun gbogbo aye wi pe kii se eta inu rara ni boolu ti oun gba pelu Neymar to fi farapa, ilu oun ni oun ja fun.
Oro Zuniga ni yii: 'It was a normal move. I never meant to hurt a
player. I was on the field, playing for the shirt from my country, not
without the intent to injure. I was just defending my shirt.'

Inu ofo nla ni gbogbo ilu Brazil wa bayii. Awon kan tile lo joko si iwaju ile iwosan ti won gbe Neymar lo boya iyanu le sele.






posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment