Smiley face

Omo Odun Meta To Ku, To Ji Dide Ti Pada Ku Patapata

Omobirin eni odun meta lati Philippines to ku lojo Eti to koja yii sugbon to pada ji dide losan ojo Abameta (ojo keji) nibi won ti n mura eto isinku re ninu ile ijo kan to wa ni Aurora. Sugbon ohun to ba ni lokan je ni wi pe omo naa ti pada ku lonii ojo Aje.


Aisan iba ni a gbo wi pe o pa omo yii lakoko ko to di wi pe o ku to si pada ji dide lojo keji. Eleyii ti won sare fun un lomi mu ti won si dapada si osibitu. Osibitu naa lo wa lati ojo Abameta ko to di wi pe o pada ku lonii.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment