Bi o tile je wi pe Obafemi ko si lara awon agbaboolu ti Stephen Keshi ko lo si ilu Brazil, sibesibe ObaGOAL gbe oriyin nla fun olukoni naa fun ise opolo ati akikanju to fihan ni ilu Brazil.
'Mo gbagbo wi pe ere boolu Nigeria sile goke ju bayii lo taa ba le mu suuru ati emi ifinsi ati otito ninu ohun gbogbo ti a ba n se.' Obafemi
0 comments:
Post a Comment