Ninu isele mii to tun waye, Soja alagidi kan ti yinbo fun omo agbero kan ni Oba Akran to wa ni agbegbe Ikeja. Soja naa ti salo bayii.
Awon eniyan to wa nibi isele naa so wi pe o le je ara lo n kan Soja naa nipa bi BRT se pa okan ninu won eleyii ti awon Soja ti di ebi isele naa le ara ilu lori bayii.

Ekunrere iroyin mbo laipe.
Awon eniyan to wa nibi isele naa so wi pe o le je ara lo n kan Soja naa nipa bi BRT se pa okan ninu won eleyii ti awon Soja ti di ebi isele naa le ara ilu lori bayii.

Ekunrere iroyin mbo laipe.
posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment