Smiley face

Won Ti Gba Ade Oba Goal Lowo Ronaldo Fun Klose

Gege bi atejade FIFA to sare jade lowo ere leyin igba ti ile Jamani fi eyin Brazil janle lojiji loju gbogbo aye, atejade yii lo salaye wi pe Ade oba eni to gba boolu wole sawon julo ninu itan boolu agbaye eleyii ti Rolnado ti n wa maya lati odun yii wa ni Miroslav Klose to je omo ile Jamani jagba lale oni [8-7-14] nibi ti Jamani ti na Brazil ni anasare pelu ayo 7 si 1; ookan.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment