Smiley face

Won Ti Pa Kunle Fadipe

A-ja-fun-eto-omoniyan to tun je agbejoro, Barrister Kunle Fadipe la gbo wi pe onise ibi kan ti lo pa sinu ile re ni Harmony Estate to wa ni Ifako Ijaiye, Lagos ni ale ojo keta osu keje odun yii. Awon osise alaabo adugbo naa pada ri okunrin agbanipa naa mu. Awon olopa si ti bere iwadii nipa isele naa.

posted from Bloggeroid

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment