Kosi ibi ti won ko ti n guyan ale, obe ni o yato sira won. Paris re e ni olu ilu France, agbado yiyan gbayi pupo.
Bi awon eniyan ba yan agbado meji lai ko meji nigba ti agbado ba jina le fa gobe.
Igba ye n le o maa gbo ti iya alagbado yoo maa wi pe 'meji sa lo yan, okan sa loko ooo.'
0 comments:
Post a Comment