Smiley face

Awon Iroyin Gbankogbi Lati Aaringbungbun Asia- Apa Kinni

Eyi ni akojopo awon iroyin gbankogbi to jade lati agbegbe Asia lagbaye. Marun-un pere ni mo mu wa fun yin lonii lati inu awon iroyin wa taa ti se akosile re tele. Ma tun maa tesiwaju afikun re laipe fun anfaani awon ti ko ri iroyin naa ka ni akoko ti awon iroyin naa jade sita. 


E maa gbe owo le awon akori iroyin isale yii lati kan won lo kookan ejeeji. E se pupo.
  1. Kayeefi Nla: Maanu Kan Dana Sun Ara Re Ni Ilu India
  2.  Ile Ounje Igbalode Ti Won Ko Si Isale Omi Okun
  3. Obo Langido N Sebi Eniyan Gidi Ni Ilu Indonesia
  4. Awon Okunrin Bi Mejidinlogoji (38) Ba Omo Odun Meedogun Sun Lojo Kan Soso Ni Malaysia
  5. Ise Awari Oko Baalu Ofurufu MH370 Ti Ilu Malaysia Wa Sopin Lonii
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment