Smiley face

Awon Oyinbo Alawo Funfun N Pariwo Rauf Aregbesola Leti Omi

Ilu Seychelles ni Kunle ati Gabriel Afolayan wa bayii. Se e ranti ofofo ti mo tu fun yin nigba kan wi pe imule egbe APC ni Kunle Afolayan. Ati wi pe oni awon ise akanse abenu kan ti n se lati fi se igbelaruge fun  egbe onigbale eleyii ti ko ti i jade. Laipe, e bere si ni ri awon ise opolo to fakiki ti omo Afolayan ti fi opolo gbe kale.
Kunle n ki Ogbeni Rauf Aregbesola ku ori ire pelu awon ore re ni ilu Seychelles
 Nje eyin mo ibi ti Seychelles wa lagbaye?


Ilu Seychelles je orileede to kere pupo lagbaye to je wi pe won le yo bi meji iru e ninu Ipinle kan soso ni ilu Nigeria. Apa ila-oorun Africa, laarin omi okun to wa laarin Africa ati Asia ni ilu naa daduro si. Ilu naa le kere loju, sugbon idagbasoke orileede naa koja ohun ti eniyan le foju pare nitori wi pe ohun to lekenka ni.

Opolopo awon eniyan ni won maa n ri irin-ajo afe (tourism) lo si orileede naa latari afefe alaafia ti n fe leti omi okun. Irin ajo afe ati ti ta awon eroja inu omi bi eja ati ede (crayfish) ni ilu naa fi n se ohun amusagbara.  
Seychelles
Bi opolopo awon ile won se ri ni yii, nitori ti ekun omiyale ba yawo aarin ilu ki omi maa ba a wo inu ile won. Fun idi eyi, won gbe awon ile naa soke fiofio.
Die ninu awon ounje won ni yii. Mi o mo oruko ti won pe awon ounje naa sugbon awon eroja inu omi naa ni pupo ninu awon ounje naa je .
Gege bi mo ti so saaju, alejo gbigba je ona kan pataki ti ilu naa ti n ri owo lati lo fun idagbasoke ilu won. Opolopo awon alejo lati orileede agbaye lo maa n sokale si Seychelles lati lo isimi won. Yato si afefe alaafia ti n fe, eja inu odo to kata senu, awon omoge to gbamuse naa wa nikale lati teyin lorun bi igba ti Sisi Caro ba bere ijakadi pelu Wizkid Omo Jayejaye loganjo oru. Sebi e mo wi pe ija Caro o daa rara, gbogbo ara ni bebe naa fi maa n ja bi Kako Onikunmekun.

Bee gele ni awon asewo ilu Seychelles se n sise won, ti awon onibara won si n royin won wi pe won le ku.  E maa je n tan yin, aye wa ni Seychelles.

Olayemi ni oruko mi. Ilu NIGERIA ni mo n gbe. Mo feran otito ati olododo eniyan. Mo si gbagbo wi pe lojo kan, NIGERIA yoo di ilu ogo; ogo re yoo si tan kari gbogbo aye.

E ku Ikale.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment