Smiley face

Awon Taye-Kehinde Omo Femi Adebayo Ni Ilu Dubai

Sebi tori omo la se n sise. Bi eniyan ba lowo ko raso to dara, bata asiko fun awon omo re lo wa okay. Taye-Kehinde omo Femi Adebayo ni yii, ilu Dubai ni awon omo naa ti n lo isimi won.
Ti ile iwe won ba wole, won yoo maa pada bo ni Nigeria.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment