Smiley face

Dubai Se e Ti Setan...P-square Mbo?

Ojo kesan-an osu kewaa odun yii ni ilu Dubai yoo maa gbalejo Peter ati Paul nibi won ti maa pidan orin fun awon ololufe won.

Ma tun maa salaye siwaju si lai pe.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment