Kaka ki kinihun se akapo ekun, onikaluku yoo se ode tie lotooto ni. Davido ati Wizkid ni won jo n fi orin pariwo si Amerika leti bayii. Bee si ni ija to wa laaarin won n fi joojumo gbona sii ni bi ajere.
Bi Wizkid ba pate orin, aimoye owo dollar nii ko lo sile. Bi Dafiidi naa ba skelewu, atomode atagba ni won wa pe wo iran omo baba olowo ni gbagede. Ki wa lo le fa ki awon mejeeji ma baa ara won ja?
0 comments:
Post a Comment