Olu ile ise ajo to n ri si boolu alafese gba ni ile Nigeria (Nigeria Football Federation) to wa ni ilu Abuja ti sadeede gbana je lonii laisi idi kankan pataki. Awon osise panapana sare debi isele naa to wa ni Wuse sugbon aimoye nnkan lo ti sofo ki won to ri ina naa pa. Iwadii si n lo lowo nipa ohun to fa ina abaadi naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment