Leburu ju leburu lo. E maa fi foonu Techno we Aifoonu rara. Dafiidi omo Adeleke nikan ni odindi baalu kan n gbe kiri Afirika bayii ni awon ilu to ti n pate orin Skelewu.
Omokunrin olorin naa ti wo ilu Togo bayii. OBO ni won gbade fun. Davido loba asiko yii.
0 comments:
Post a Comment