Se ri awon Oluya ti mo n so yii, ko si ohun ti won ko le ya
rara. Gbogbo ohun ti won ba ti ri ni won ya lode. Okan ninu awon
Oluyaworan ile ise iroyin Magasiini Ovation Agbaye lo ya aworan yii.
E ri wi pe Oluya naa gbiyanju gidi gan-an? Ki eniyan to le ri agbedemeji aye atorun ya, ise kekere ko o.
0 comments:
Post a Comment