Omo agbaboolu Cameroon, Albert Ebossé ti n sise aje boolu gbigba ni ilu Algeria ni awon onworan elemi esu kan ti fi okuta fo ori re danu ti omo okunrin naa si gbabe ku leyin ti won gbede osibitu lojo Satide to koja yii [23-8-14].
Egbe agbaboolu JS Kabylie ti Albert Ebossé lo padanu ifesewonse nile won eleyii to keyin liigi ilu Algeria, ibinu yii lo mu awon onworan fi okuta tu won ka.
Egbe agbaboolu USM Alger ti won na JS Kabylie mole ni won se ipo kinni nigba ti JS Kablie se ipo keji ninu liigi ilu Algeria.

0 comments:
Post a Comment