Smiley face

'Ara Nla Maa San Ni Ilu London Ati Manchester'- Wizkid

Egberun oko, egberun ada won ba oke sota, oke o je bee ni oke o mu, sibesibe oke lo pada bori gbogbon won.

Wizkid omo aye ti iku aye ko gbodo pa ti fesi ranse si awon ololufe re to wa ni Ilu London wi pe ara orin maa san.

Ojo kerindinlogun [26-09-12] ni Ayo maa korin ni ilu London nigba ti Manchester yoo ma dun ni ojo kejidinlogbon [28-09-14].

#yaga

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment