Fiimu to gun gan-an ni mo gbo ri, nibayii, aso iyawo to gun ti o lopin ni Jing Mei lati ilu China fi se igbeyawo re. Awon ore iyawo bi ogoji ni won ba ko aso re bo leyin eleyii to fe e gun to nnkan be egberun meta maili seyin.
E gbo ohun ti iyawo so nipa aso igbeyawo re:
"It started off as a mad idea and then we thought we could actually make it happen.
We're both delighted with the result and we are definitely going to contact Guinness World Records to get them to agree that this is an official record breaking dress."
Home / Uncategories / Aso Igbeyawo Jing Mei Ti Ilu China Ti Fe Wo Inu Iwe Itan Guinness World Records
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment