Walahi! Ankara ni mo koko pe aso yii. Igba ti mo wo daada ni mo ri wi pe kii se ankara. Orisi awo meta lo jade ju lara aso naa. O si je awon aso ti maa n ran bi roba.
Aso naa le mo o lara bebe, eleyii to je ki gbogbo igun omo naa jade daada. Atiwaju ateyin lo ta bokua bi isu Abuja. Ibadi bi ile tiiro ko si soro lati ri rara.
Ara oto tun ni irun ori re, eleyii to fe e gun de ibadi. Sebi won ni ibadi laye wa. Ti aye ba wa ni ibadi looto, ti Nicki tun yato.
Aye atorun ni omo naa fi n joko bi apoti. Eniyan si le pe ni apoti aje. Sebi ohun to ba jora la fi n wera won; epo epa jo posi eliri, ologinni jo amotekun.
0 comments:
Post a Comment