Ohun to daju ni wi pe Dayo Amusa gbadun ara re gidi gan-an ni awon asiko to fi lo sinmi ni ilu London. O si je idunnu fun oun gan-an lati ri ile baba re pada.
Ebiripo ati obe egusi ni Dayo n se lori ina. To ba ti jina, gbogbo yin naa le ma towo ninu ounje naa. Erkk
0 comments:
Post a Comment