Smiley face

[Foto] Sikiratu Sindodo Oloju Kolirosi

Laipe yii ni mo se afihan ode ariya Sule Alao Malaika olorin onifuji nibi to ti n se ifilole awo re tuntun to pe ni SUPER STAR.

Aimoye awon eniyan lagbo amuludun lo peju-pese sibe, lara won ni Sikiratu Sindodo. Afikun awon aworan oserebirin naa ni yii, eleyii to ya ko to kuro nile.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment