Smiley face

'Gbogbo Awon Omo Oloso Ilu New York Ni Won Fe Kopa Ninu Fidio Orin Mi'- Davido

Ilu Amerika ni Davido ti gbe n paro ara re lowolowo bayii pelu awon ololufe re. Bi o tile je wi pe omo Adeleke n sere lode ariya, sugbon fidio orin re to lo ya ni Amerika je pataki julo ninu irin ajo re.

O tile so wi pe aimoye awon omo oloso ni won fe lati foju han ninu fidio orin oun.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment