Ohun kan ti ko ye mi ni wi pe, se komu naa ja fun rare ni abi omo naa lo ja lati fi soge?
Gbogbo awon eniyan ti won wa ni pati ijo naa ni won gbe kamera dani. Bi won se n ya iwaju Maheeda ni won tun ya gbogbo fiimu ti omo naa si sile leyin.
Emi diju temi ni o. Mi o le wa foju ko ikokuko. Ki eniyan ma lo foju ko Ebola.
Robis ni gbogbo eleyi ooo waliahsiri irole aye de
ReplyDelete