Ibadi to lokiki ju lagbaye ni eyi ti mbe leyin Kim Kardashian ti ilu Amerika. Aimoye owo ni omobirin yii ti fi ibadi re pa nipa sise afihan igbe aye ara re loju aye lori telifisan ati ipolowo oja fun awon magasiini alaso oge ati eso ara. Bakan naa ni won tun sanwo fun un to ba fi ijoko ye awon alariya si lagbo faaji.
Olayemi Oniroyin pinnu lati be ibadi naa wo lonii pelu die lara awon atejade iroyin ti a ti gbe sita tele nipa ibadi olokiki naa. Mo lero wi pe e o gbadun re gidigidi.
0 comments:
Post a Comment