Smiley face

'Mo Setan Lati Pada Soju Ogun'- Omo Obasanjo Ti Boko Haram Ta Nibon Loju Ija

Adeboye Obasanjo ti pinnu lati pada lo ba Boko Haram woya ija nikete ti oun ba ti gbadun. Adeboye ni ota ibon awon Boko Haram ba nibi ti awon soja bi merindinlogbon ti ku.

#Iroyin Ni Soki

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment