Se ara le tabi ko le ti kuro loro eni won ba lori igi ope. Leyin awuyewuye idubule aisan Bola Tinubu ti awon egbe PDP fi esun kan APC wi pe n se ni won gbe baba naa pamo latari orisi aisan ti n se eleyii ti won lo buru jai ti won ko si fe ki ara ilu mo si i.
Ilu London ni Tinubu wa ni gbogbo akoko yii nibi to ti n gba itoju. Bi o tile je wi pe won ko je ki enikeni mo osibitu ti won gbe lo, sugbo baba naa ti pada wale. Poun-poun lo si n ta bi eni to lo Energy 2000, koda Oga Dele Momodu pade re lode leyin to de pada si ilu Nigeria.
0 comments:
Post a Comment