Edumare lo mose asela laye. Ati igba ti awon omo ibeji Okoye ti wo ilu Namibia lo ti je wi pe won ko ti loju orun mo- joojumo ni won korin, joojumo ni won Jo.
Ko wa sibi ti won ti le korin, awon ero maa yapa ni. Olorun nikan lo mo iru aworo buruku ti won lo, o si le je kadara ni i sise fun won. Errk
Ole nikan laye o gba, ibi gbogbo lo gba P-square alagbara.
Akiyesi: Ninu aworan, okan ninu won kawo lori nigba to ri opolopo awon eniyan ti won ya wole. Ati ibi kan to ti n dupe fun emi ife ati ayesi ti won rigba lowo awon ololufe won ti won jade wa woran ere won.
Ori emi gan-an wu nigba ti mo wo fidio ere won, inu mi si dun.
0 comments:
Post a Comment