Igbeyawo Tiwa Savage ati Tunji Balogun t'esu gbiyanju lati baje sugbon ti Oba Oke ko je ti pada pe odun kan pelu ayo ati alaafia.
Tiwa Savage lo sori ero Instagram re lonii pelu ope fun Olorun oba to mu yigi re duro sinsin pelu Tunji.
Awa naa ba toko-taya naa dupe. Ina ife ko ni ku, ayo ife ko ni baje. Amin.
Akojopo Awon Aworan Irawo Ti Won Peju Sibi Ayeye Igbeyawo Tiwa Savage http://www.olayemioniroyin.com/2013/11/akojopo-awon-aworan-irawo-ti-won-peju.html
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment