Won Ti N Ko Oku Awon Eniyan To Sagbako Ninu Baalu AirAsia To Ja
Won ti bere si ni ko oku awon eniyan to sagbako ninu baalu AirAsia pada wa sile nigba ti won ri ibi ti baalu na jasi ninu omi okun. Oku ati awon eru awon ero oko baalu naa ati awon eroja ara baalu naa ni won ti n ko pada wale bayii.
0 comments:
Post a Comment