Smiley face

Awon Ero Bi Ero Mecca Jade Wa Wo Buhari Ni Ilu Kano Lonii

Ilu Kano gbalejo Muhammadu Buhari lonii nibi to ti n so fun awon eniyan wi pe yato si ibo won ti won fe di, won tun gbodo ri daju wi pe won daabo bo ibo won daada lowo awon ti won fe se madaru


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment