Smiley face

"Buhari Kii Se Ojelu" -Obasanjo

Nibi abewo kan ti awon asaaju egbe APC se si Aare Nigeria nigba kan ri, Olusegun Okikiola Mattew Aremu Obasanjo lo se alaye Buhari gege bi eniyan kan ti ko ni abuku kankan lara.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment