"Inu mi dun lati ko lo sinu ile ara mi ti mo fi owo ara mi ko, ayo nla lo je fun mi" Ini EdoAgbegbe Lekki ni ilu Eko ni ile tuntun naa wa, aimoye awon eniyan lagbo amuludun ni won si peju sibi ayeye isile naa.
[Foto] Ayeye Isile Tuntun Ini Edo Larinrin
Won ni igbin kii kere lai ma ni ile lori. Oserebirin, Ini Edo ti n fi ope fun Oluwa fun aseyori ile tuntun re ti oba mimo se fun un.
0 comments:
Post a Comment