Smiley face

Jay Z Pelu Beyoncé Ni Ilu Thailand

Sebi omo to ba n sise deede o ye ko ni akoko igbadun ni toko-taya olorin takasufe ilu Amerika, Jayz ati Beyonce fi oro naa se pelu bi won se gba isimi won silu Thailand. Bi eniyan ba ri owó se faaji, faaji a maa dun bi aye ọlọba.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment