Smiley face

Jonathan Ati Buhari Fijo Atayo Pade

 
Aare Jonathan pade Buhari nibi ipade kan to waye ni ilu Abuja nibi won ti n se ipade bi eto idibo ti yoo waye losu keji odun yoo se lo nirowo-rose. Erin ati idunnu ni awon oludije fun ipo aare mejeeji naa fi pade ara won. Awon Yoruba ni erin kii se ife. Ati wi pe oju lari ore o denu. Nje a le gba wi pe bee lori pelu awon oludije mejeeji yii? Sugbon sa, ti won ko ba fi erin pade, se mo fe ki won maa ja gidigbo ni?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment