Smiley face

Madonna Ti Soro Lori Ohun Ti Iluminati Je


Iluminati je egbe kan ti opolopo awon eniyan lagbaye gba wi pe o je egbe okunkun eleyii ti awon olorin agbaye n darapo mo lati ni okiki ati ola. 

E maa si gbagbe wi pe aipe yii ni Madonna gbe orin kan jade eleyii to pe akole re ni Iluminati eleyii to tun bo fa opolopo awuyewuye. Ohun ti Madonna so ni yii:




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment