Ohun tuntun
sẹlẹ nibi igbeyawo laarin Laide ati Anthony to waye lopin ose to koja. Igba àkókò to fun iyawo lati fun ọkọ rẹ lounje akọkọ jẹ loju gbogbo ero, iyawo sebi ọmọ Yoruba gidi loba kunlẹ fun Anthony lounje. Igba ti won ni ki oko naa fun
iyawo lounje ni oko naa ba fi ikunle bẹ. Awon eniyan ni ifẹ lopoju ki won ma ba
Anthony wi.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment