Okunrin kan ti oruko re n je Ajanlekoko James eleyii ti iwadii fi ye mi wi pe o je ololufe egbe PDP lo gbe aworan okunrin kan ti oruko re n je Oguntimehin Olakunle Peter si ori Facebook to si beere si ni se epe fun nitori okunrin naa bu gomina kan.Titi di akoko yii, mi o ti le so gomina ti Oguntimehin Olakunle Peter bu to fi di ohun ti Ajanlekoko James fi n rojo epe le e lori.
![]() |
Oguntimehin Olakunle Peter |
"Ajanlekoko James: Oguntimehin olakunle Peter. Iya re ti fi obo jona. Iwo ko le se orire laye laye toripe aye re ti baje . iwo eniyan jati jati omo eran , o npe gomina wa ni Oloriburuku , lati eni lo , owo re ko ni de enu re . iya ni ti eran ati kiri , iya loju re a ma ri . Gbogbo inkan ti o ba dawole ko ni je fun e . Aye re daru lati oni lo . Gbogbo inkan daradara ti o ti se ma baje . Afi ti o ba toro aforiji lowo Olorun ti o ba tender public apology for abusing the governor . you will die wretched. all what you laboured for will perished .Iwo ko le ever di ordinary councillor titi aye yio o fi pare . Iwo ko ni de ipo ola . You will be deported losan gan gan . Your rape case will be visited ."
0 comments:
Post a Comment