Awon egbe awon omo Gambari kan loke oya ti leri lati je ile ise telifisan AIT run ti Buhari be se bee padanu ibo Aare ti n bo pelu awon iroyin orisirisi ti ile ise naa n gbe jade lati fi ba GMB loruko je.
Won ti ko ero won sinu leta, ohun to ba si le mu Hausa feebo ko leta, see mo wi pe oro ti kuro ni waza nu-un.
0 comments:
Post a Comment