Smiley face

Iroyin Pajawiri: Baalu Ja Ni Ilu Taiwan

Iroyin ti kan wi pe baalu kan ti ja sinu odo kan ni ilu Taiwan bayii. Awon eniyan bi metalelaadota (53) ni won si wa ninu baalu naa.

Ekunrere iroyin mbo laipe
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment