Ijamba oko kan waye ni agbegbe Festac ni ile Ilu Eko. Awon toko-taya ti won wa ninu oko na ni won ni won daribo lati ile ile ijo ti won ti lo gbadun ara won. Oju ese ni iyawo ku, nigba ti oko wa lesan kan aye, ese kan orun bayii. Ogbonnaya Merije ni won pe oruko idile naa.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)


0 comments:
Post a Comment