E je n sare se afihan die lara awon foto awon amuludun to wa lowo mi ke fi fun oju yin lounje. yato si oju, mo tun ti pese ounje aladidun fun yin, eleyii ti e o gbadun doba. E maa wo awon aworan naa bo si isale.
Adewale Johnson (Oko Toyin Aimakhu) ni ibudo isere tiata
Ojo-ibi Ayo Animashaun, alase ati oludari HipTV to waye losẹ to koja (Ayọ ni eniketa lati apa otun)
Iyawo Joseph Yobo, Adaeze n soo ara re. Omobirin naa fe ka mo wi pe oun ti loyun. Oloruno o so layo
Dayo Amusa, oserebirin onitiata
Tonto Dike, oserebirin onitia geesi
Mide Funmi Matins
Toyin Aimakhu ati oko re ati Yinka Ayefele
E wa ba mi jeun
0 comments:
Post a Comment