Smiley face

Awon Gbajugbaja Iroyin Apa-Keji

Isẹ Iroyin Ati Isubu Awọn Akọni


Aimọye ìgbà ni mo maa n rò ohun ti mo le fi isẹ́ iroyin we. Awọn ohun tó jọra pẹ̀lú isẹ́ iroyin tó wà ni awujọ wa jẹ ohun to maa n fun mi ni òye nipa orisii Isẹ Iroyin to gbamuse ati ipo to yẹ ki isẹ iroyin wa gan-an ni gidi. Sebi ohun to ba jọ ara won ni a fi n wéra wọn. Awọn Yoòbá ni won se apejuwe bi èpo ẹ̀pà se fara jọ póósí ẹ̀lìrì. Eniyan to ba fi ori ológbò se apejuwe àmọ̀tẹ́kùn, a kò le pe irú ẹni bẹẹ ni amukunmẹ́kọ lailai.

Lára ohun tó yé mi yékéyéké nipa isẹ iroyin ni wi pe, isẹ iroyin tayọ ọgbọ́n àtinúdá lasan gẹgẹ bi orisii ẹ̀bùn kan pataki ti àwọn onkòwe alatinuda gbámú gẹgẹ bi ohun amusagbara gbòógì. Isẹ Iroyin jẹ akojọpọ èròjà lati àwùjọ eleyii  ti a kó padà fun àwùjọ nipa ọgbọn atinuda ati ète isẹ iroyin yálà lati fi salaye ọ̀rọ̀, isẹlẹ tabi lati tan ìmọ́lẹ̀ si òye awon eniyan nipa awujọ ati ìgbé ayé wọn lapapọ. 

E tesiwaju [NIBI]

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment