Smiley face

Awon Omo Egbe Okunkun Ifafiti Eko Ti Pa Ara Won

Omokunrin yii ni awon kan ti won seese ki won je omo elegbe okunkun seku pa ni nnkan bi ago mejila oru ana yii ninu ogba ile iwe Ifafiti ti Ilu Eko. Awon kan ni o seese ki omokunrin naa je okan lara awon omo egbe okunkun naa. Sugbon ko ti si aridaju titi di akoko yii.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment