Maanu yii ni owo tẹ ni ilu Abuja nibi o ti n gbiyanju lati ji moto gbe salọ. Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni ti 'dihona'. Okunrin naa dọgbon bi eni ba enikan soro lori ago nigba to n gbiyan korokoro gbogbonise kan lati fi si ileku motor naa. Awon eniyan ti won wa ni agbegbe naa le sare, won si ko logbon ti o ni gbagbe lailai leyin naa ni awon olopa wa mu lo si ago won.
Moto ti maanu naa fe ji ni yii |
0 comments:
Post a Comment