Gaari Ijebu Ajumose gbe lenu, o see mu bakan naa ni eniyan le fi tẹba to gbona. Sebi awon Yoruba naa ni won wi pe ti ounjẹ ba ti kuro ninu isẹ, isẹ buse. Pelu gaari broda Isiaka, kosi ebi mo ni Ipinlẹ Oyo.
Gba gaari agolomerin koo dibo...
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment